Ajo INEC Yoo Samulo Owo Taleni Odunrun Billion Naira Feto Idibo 2023

Ajo eleto idibo ile yii, INEC, ni ohun yoo nilo billionu lona odunrun ole maru naira, fun eto idibo gbogbo odun 2023.

Alaga ajo INCE, Ojogbon Mahmood Yakubu so eyi lasiko ti n farahan niwaju igbimo tekooto ile feto isuna.

O salaye pe ogorun billionu naira ninu owo ohun ti je fifi sowo sajo ohun tosiku billionu marunlenigba naira.

Igbimo tekoto ile eto isuna, ni wiwoye si eto idibo gbogbo odun 2023, kesi alaga ajo INCE, lati gbe alakale  inawo naa siwaju ile.  Kiwon le seto re si nu aba eto isunaa odun 2022 ti won fe fi sowo loni yi.

Net / Idogbe

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *