Awon Giwa Ile-Eko Giga Nile Yii Ti Ro Ijoba Apapo Ati Tipinle Lati Wa Nkan Se Awon Ti Ma Nsuyo Larin Ijoba Atawon Oluko Eyi Ti Ma N Yoori Sii Iyanseloodi.

Eyi Waye Nibamu Pelu Bi Won Sen Wa Ona Ibasepo Todan Moran Pelu Egbe Awon Oluko, Ile-Eko Giga, Asuu, Pelu Afojusun Lati Mu Eto Eko Duro Ree Nile Yi.

Alaga Igbimo Awon Giwaa Ile-Eko Giga, Ojogbon Samuel Edo-Umi – Ekumo So Eyi Lasiko To Sabewo Sii Aare Egbe Asuu, Ojogbon Victor Osodeke Lati Soro Lori Awon Ipenija To Nkoju Eto Eko Lawon Ile-Eko Giga Vasity Nile Yii.

Ojogbon Edo-Umi-Ekumo, Nii Ibase Po Ohun Yoo Tun Fojusun Ona Abayo Sawon Ipenija Ile-Eko Giga Ile Yii.

Aare ASUU, Ojogbon Victor Osodeke Gboriyin Fun Adari Egbe Awon Giwa Ile-Eko Giga Fun Igbese Akin Re.

Net / Idogbe

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *