Ajo UNICEF pelu ibasepo Ajo ti kii se tijoba ni won ti gbe iko to yo ri daju pe opin deba didabe fomobinrin nileyi lele.

Ogaagba ajo ti kii se ti joba, ‘One life initiative for human development Ogbeni Sola Fagorusi lo soro yi di mimo lasiko to n kopa lori eto iforowa nilenuwo ilese Premeir FM, ti won pe ni Straight Talk.

Ogbeni Fagorusi se lalaye pe didabe fomobinrin to lese nle leka eto ilera, tokasi pe igbimo ti yo fofin to dee mule ni yo malo yika ipinle ati ijoba ibile nile yi, lati le fopin si asa ohun.

Ogbeni Fagorusi tenumo pe didabe fomobinrin lewu lopolopo ati wipe oniruru o fun lowa n kale lati fi mu enikeni to ba ta pa si ofin to I tee to omo luju mole

Kehinde/Afonja

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *