Awon osise leka irin ajo ofurufu ni won ti sewele, erongba won lati gunle iyanselodi eyi ti won fe bere loni.
Igbese yi lo waye leyin ti won ti fenu ko pelu awon osise ati ajo to n risi irin ajo ofurufu.
Igun mejeeji lo fowo si afenuko leyin ipade lati yanju aawo, eyi ti alakoso foro ise ati igbani sise Senator Chris Ngige lewaju re.
Ninu ipade ohun ni won ti jiroro lori bi won ko se ti ri owo to kerejulo gba leka naa lati odun 2019, to fi mo bi won lo se fowosi liana atunto lori ise leka naa.
Ninu atejade eyi ti agbenuso fun ajo to n mojuto ise, Ogbeni Charles Akpan fowosi so pe ipade naa, fenuko pe, nigbati yio ba fi di ipari saa akoko lodun 2022, ajo naa yio ri daju pe owo awon osise te gbogbo nkan ti won bere fun Senator Ngige leyin ipade so pe, won yo samulo owo osu to kerejulo bere lati osu kerin ojokejidinlogun odun.
Net/Okareh/Afonja


