Nidi  igbiyanju ati mu agbega ba ipese isu lopo yanturu , ile ise ton risi idagbasoke ise agbe nile olooru, IITA ti se agbekale ona igbalode fun ipese eebu isu ti kokoro ko ni le je .

 aseyori yi lo jeyo latara akanse ise ti won da pe ni agbega isu fun ipawo wole ati ipese ounje lopo yanturu lapa iwo oorun ile africa eyi ti won da peni

lasiko eto naa to waye nilu ibadan , oludari ileese agbe IITA fekun iwo oorun ile africa, ojogbon Micheal abberton salaye wi pe akanse ise naa lo wa fun ati koju ipenija awon agbe widi ati ri ojulowo eebu isu gbin.

o wa ro gbogbo awon toro naa gberu pe ki won je ki awon agbe maa ri eebu isu  lorowoto won.

lara ohun  ti waye nibi eto naa ni fifa eebu isu to din e ni egberun meje kilo, to je orisi meji le awon agbe lowo fun gbingbin.

Fasasi/ Salaudeen

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *