Home Posts tagged Abẹ́rẹ́ Àjẹsára
News Yoruba

Wọ́n Ti Gba Ìjọba Àpapọ̀ Níyànjú Láti Sàgbékalẹ̀ Òfin Kan Tí Yóò Pa Abẹ́rẹ́ Àjẹsára Gbígbà Ní Dandan Fáwọn Ọmọdé

Wọ́n ti rọ ìjọba àpapọ̀ láti sàgbékalẹ̀ àwọn òfin kan tí yóò pa abẹ́rẹ́ àjẹsára ní dandan fáwọn ògo wẹrẹ, lọ́nà àti dábobo wọn kúrò lọ́wọ́ àwọn àrùn àtàisàn lọ́kọ́kan òjọ̀kan. Akọ̀wé àgbà àjọ tón bójútó ètò ìlera alábọ́dé nípinlẹ̀ ọ̀yọ́ Dókítà Muyideen Ọlatunji ló sọ̀rọ̀ yíì di mímọ̀ lákokò Continue Reading
News Yoruba

Ilẹ̀ Nàijìrìa Ti Tẹ́wọ́ Gba Abala Àkọ́kọ́ Abẹ́rẹ́ Àjẹsára Tón Dènà Àrùn Covid-19

Bí ilẹ̀ Nàijírìa se ti ńtẹ́wọ́gba abala àkọ́kọ́ abẹ́rk àjẹsára tí yóò máà dènà àrùn covid-19 lágọ ara lóni, àwọn olùgbé ìlú ìbàdàn kan ti késí ìjọba àpapọ̀, láti sese dédé lórí ọ̀rọ̀ pínpín abẹ́rẹ́ àjẹsára ọ̀hún. Ìlú ìbàdàn niwọ́n ti sọ̀rọ̀ yíì di mimọ̀ fákọ̀ròyìn ilé-isẹ́ wa, méjì lára àwọn olùgbé náà, ọ̀gbẹ́ni Owolabi […]Continue Reading