Olori orile-ede yi nigbakanri, Ogagun feyinti Abdulsalami Abubakar n pe fun gbigba adua fun alaafia ati itesiwaju ninu isokan orile ede Naijiria. O soro yi ninu oro ikini to fi ranse sawon Musulumi lori ajoyo odun Eid-el-kabir. Ogagun feyinti Abubakar, sope wiwa nisokan ile yi ni o se pataki to Continue Reading