Ìgbìmọ̀ tẹkótó ilé asòfin kejì lórí ètò ìlera ti fọwọ́sí titọwọ àjọ elétò ìlera adójútofo, NHIS, bọmu àwọn isẹ́ àkànse tóníse pẹ̀lú ètò ìlera táwọn asòfin máà ń se lẹ́kùn ìdìbò kóòwá wọn.

Alága ìgbìmọ̀ tẹkoto le asòfin kejì náà, ọ̀mọ̀wé Tanko Sanunu ló kéde yíì nílu Abuja lákokò tákòwé àgbà àjọ NHIS, ọ̀jọ̀gbọ́n Muhammed Sambo farahan níwọnju ìgbìmọ̀ náà fọrọ àbá ètò ìsúná ọdún 2022.

Ọmọwe Sununu sàlàyé pé, bí isẹ́ àkànse tónsí pẹ̀lú ètò ìlera láwọn ẹkùn ìdìbò kóòkan bá ń gba abẹ kọjá, yóò fáwọn tón gbé láwọn agbègbè ìgbèríko atẹsẹ kuku lánfaní látara ètò ọ̀hún láifi teyikeyi ipose.

Nínú ọ̀rọ̀ tákọ̀wé àgbà àjọ, NHIS, ọ̀jọ̀gbọ́n Muhammad Sanubo, sọpé, àjọ náà ti sàgbékalẹ̀ ètò kan, tí yóò fẹnikookan àwọn ebi lanfani àti sanwó lórúkọ àwọn èèyàn agbègbè kóòwá wọn.

Folakemi Wojuade

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *