Home Posts tagged Akeko
Yoruba

Ìjọba ìpínlẹ̀ Ògùn sèlérí láti fìyàjẹ akẹ́kọ́ọ̀ yóòwu tó bá hùwà àitọ́ láwọn ilé-ìwé

Ìjọba  ìpínlẹ̀ Ògùn ti kéde pé, wọn yóò lé èyíkèyí àwọn akẹ́kọọ tó bá domi àláfìa ìkẹ́kọ́ọ̀ rú, láwọn ilé-ìwé gbogbo tó ń bẹ nípinlẹ̀ náà kúrò nílè wé. Alákoso fétò ẹ̀kọ́ ìmọ̀ sáyẹ̀nsì àtìmọ̀ ẹ́rọ nípinlẹ̀ Ògùn, ọ̀jọ̀gbọ́n Abayọmi Arigbabu ló sísọ lójú ọ̀rs yíì nílu Abẹokuta lákokò tón Continue Reading