Home Posts tagged Akinyẹle
Yoruba

Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Ńfẹ́ Kí Àlàyé Wà Lórí Ẹ̀sùn Ilẹ̀ Gbígbà Níjọba Ìbílẹ̀ Akinyẹle

Lẹ́yìn ẹ̀sùn gbígba ilẹ̀ àtàwọn ilé lágbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Akinyẹle tí wọ́n fi kan ìjọba ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́, ilé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ti késí ọ̀gágba wọnlẹ̀wọnlẹ̀ tótúnjẹ́ akọ̀wé àgbà, nílesẹ́ tón rísí ilẹ̀ àti ìdàgbàsókè àwùjọ nípinlẹ̀ yí. Nínú àbá èyí tí ọ̀gbẹ́ni Taofeek Kẹhinde tón sojú Continue Reading