Home Posts tagged Àkúrẹ́
Yoruba

Àwọn araalu bèrè fún gbígba isẹ́ àgbàse òpópónà Àkúrẹ́ sí Adó Èkìtì kúrò lọ́wọ́ agbasẹ́ tó ńséè

Àwọn olùgbé ìpínlẹ̀ Òndó àti Èkìtì ti sèwọde wọ́ọ̀rọ́wọ́ lórí bí wọ́n ti se pa isẹ́ sísọ opopona tó lọ láti ìlú Àkúrẹ́ sí Èkìtì oní billiọnu méjìlélógún naira tí èyítí ìjọba àpapọ̀ ti gbé fún agbasẹ́ se láti bí osù mẹ́ẹ̀dogún sẹ́yìn. Àwọn olùwọ́de náà ni wọ́n yabo agbègbè igboba ni to si Continue Reading