Home Posts tagged Alakoso fétò ẹ̀kọ́ kejì
Education

Sísí ilé ẹ̀kọ́ padà, alákoso sọ ìlànà a ńtẹẹlé

Alakoso fétò ẹ̀kọ́ kejì, Emeka Nwajiuba ti sọ wípé àwọn ilé ìwé léè sílèkùn padà nílẹ̀ yí lẹ́yìn tí wọ́n bá ti ka òfin tó de lílọ bíbọ̀ láàrin àwọn ìpínlẹ̀ nílẹ̀. Alákoso ọ̀ún sọ̀rọ̀ yí níbi ìjábọ̀ ojoojúmọ́ lórí ibi tí ǹkan dé dúró lórí ọ̀rọ̀ covid 19 tí ìgbìmọ̀ amúséyá ìjọba àpapọ̀ nílu […]Continue Reading