Home Posts tagged alákoso ilésẹ́ ọlọ́pa nípinlẹ̀ ọ̀yọ́
Yoruba

Gómìnà Makinde ti sèlérí láti sèpàdé pẹ̀lú alákoso ilésẹ́ ọlọ́pa ípinlẹ̀ ọ̀yọ́

Gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́, onímọ̀ ẹ̀rọ Seyi Makinde ti sèlérí láti sèpàdé pẹ̀lú alákoso fún ilésẹ́ ọlọ́pa nípinlẹ̀ ọ̀yọ́, ọ̀gbéni Joe Nwachukwu, láti ridájúpé ìgbésẹ̀ tóòyẹ jẹ́ gbígbé fún àbò gbogbo-gbò.  Ó sọ̀rọ̀ yíì nílu ìbàdàn, lásìkò tó ńbá àwọn olùfẹ́húnúhàn tó ń gbèèrò láti dàànà sún Continue Reading