Yoruba

Gómìnà Makinde ti sèlérí láti sèpàdé pẹ̀lú alákoso ilésẹ́ ọlọ́pa ípinlẹ̀ ọ̀yọ́

Gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́, onímọ̀ ẹ̀rọ Seyi Makinde ti sèlérí láti sèpàdé pẹ̀lú alákoso fún ilésẹ́ ọlọ́pa nípinlẹ̀ ọ̀yọ́, ọ̀gbéni Joe Nwachukwu, láti ridájúpé ìgbésẹ̀ tóòyẹ jẹ́ gbígbé fún àbò gbogbo-gbò.

 Ó sọ̀rọ̀ yíì nílu ìbàdàn, lásìkò tó ńbá àwọn olùfẹ́húnúhàn tó ń gbèèrò láti dàànà sún ilésẹ́ ọlọ́pa Testing ground Idi-apẹ ìbàdàn.

 Lásìkò tó ńbá àwọn ọ̀dọ́ tí ńnú bíì ọ̀hún sọ̀rọ̀, Gómìnà Makinde pè fún àláfìa tó sì sèlérí láti bójútó ìréfun wọn.

  Gómìnà Makinde sàlàyé pé, ètò isẹbo tó ńléwájú tí sètò báwọn èèyàn tó ní àwọ̀ kan tàbí omin pẹ̀lú ìwà ipá ọlọ́pa yóò se máà fíì lsùn wọn hàn, pẹ̀lú àlàyé pé ojú-óòpó ayélujára kan tí jẹ́ sísí láti fẹ̀sùn wọn sọwọ́.

Adebisi/Idogbe

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *