Home Posts tagged Àrẹ Muhammadu Buhari
Yoruba

Àrẹ Buhari pè fún ìsọ̀kan báwọn mùsùlùmí se n sọdún ìtúnu àwẹ̀

Àrẹ Muhammadu Buhari ti késí àwọn èyàn nílẹ̀ Nàijírìa láti tẹ̀síwájú nínú wíwà láfifìa, ìsọ̀kan àti fífi ìfẹ́ hàn léyi tí wọ́n gùnlé lásìkò osù Ramadan. Àrẹ sọ̀rọ̀ yí nínú ìwé tó fi síta nípasẹ̀ agbẹnusọ rẹ̀ Mallam Garba Shehu nílu Abuja. Àrẹ Buhari kí gbogbo èyàn ilẹ̀ yi pátápátá, tófimọ́ àwọn Continue Reading