Home Posts tagged Asòfin
News Yoruba
Gbogbo ǹkan ló pakasọ lówurọ òní nílé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ nítorí bágbe àwọn òsìsẹ́ ẹ̀ka ilé ìgbìmọ̀ asòfin nípinlẹ̀ yíì, se gba ẹnu ọ̀nà àbáwọlé sílé ìgbìmọ̀ asòfin náà tìpa. Ìgbésẹ̀ yíì ló wáyé níbamu pelu olùfẹ̀hóhàn tíwọ́n gùnlẹ̀ èyí tíwọ́n fin bèèrè fómìnira ètò ìsúná fáwọn asòfin ọ̀hún. Oníròyìn ilé-isẹ́ Radio Nigeria, tó […]Read More...
Load More