Iyawo Gomina Ipinle Oyo, Arabinrin Tamunominimi Makinde ti kesi awon omo ile Nigeria pe ki won dide atileyin fawon obinrin to lugbadi ijamba lasiko abe dida fomobirin. Arabinrin Makinde soro imoran yi lasiko eto ayajo fifopin si abe dida fomobinrin fun todun yi. Iyawo Gomina, eni ti alakoso Continue Reading
Gẹ́gẹ́bí ara ọ̀nà láti fòpin sí ètò àbò tó mẹ́hẹ nílẹ̀ ìbàràpá, adarí ilé ìgbìmọ̀ asòfin nípinlẹ̀ ọ̀yọ́, ọ̀gbẹ́ni Adebọ Ogundoyin ti gbé alùpùpù mẹdogun tuntun fáwọn ẹ̀sọ́ alábo tójẹ́ ọmọbíbí ilẹ̀ ìbàràpá. Nígbà tón gbé àwọn alùpùpù náà fáwọn olórí agbègbè àti àwọn asíwájú ẹ̀sọ́ alábo lágbègbè nílesẹ́ ọlọ́pa tówà nílu Èrúwà, ọ̀gbẹ́ni Ogundoyin […]Continue Reading