Home Posts tagged àwọn on ìjagun
Yoruba

Àrẹ Buhari ńfẹ́ àmúlò fífi òdiwọ̀n si lílò àwọn on ìjagun nílẹ̀ adúláwọ̀.

Àrẹ Muhammadu Buhari ti rọ àwọn asájú nílẹ̀ adúláwọ̀ láti mú àgbéga bá sísàmúlò, mímú òdinwọ̀n bá lílò ìjagun olóró, kí ìsọ̀kan àti àláfìa le débá ètò àbò láwùjọ lápapọ̀. Àrẹ Buhari sọ̀rọ̀ yí lásìkò ìpàdé pàtàkì ẹlẹkẹrinla, ilẹ adúláwọ̀ ni mímú àgbéga bá àláfìa, ètò àbò, ìsọ̀kan, àti mímúkí Continue Reading