Home Posts tagged Covid-19 vaccine
Yoruba

Ìjọba Àpapọ̀ Yio Bẹ̀rẹ̀ Gbigba Abẹ́rẹ́ Àjẹsára Covid-19 Miràn

Àjọ tó ńrísí ọ̀rọ̀ ilé ìwòsàn aláàbọ́dé nílẹ̀ yí ti sọ wípé orílẹ̀ èdè yi yio gba abẹ́rẹ́ àjẹsára COVID-19 Pfizer-Biontech, Modena àti oxford Astrazenica láàrin osù yí sí osù kẹsan ọdún yí. Adarí àgbà fún àjọ náà, Dókítà Pheza Shuab ẹnití ó sọ̀rọ̀ yí di mímọ̀ nílu Abuja sọ wípé oníruru àwọn abẹ́rẹ́ àjẹsára […]Continue Reading
Health

Lagos Vaccinates 12,720 People in 48 Hours

The Lagos State Government says it has vaccinated 12,720 people with the AstraZeneca COVID-19 vaccine 48 hours after the vaccination exercise commenced in the state. The state Commissioner for Health, Prof. Akin Abayomi, made this known through his verified Twitter account @ProfAkinAbayomi, on Thursday while giving the state’s COVID-19 Vaccination update for March 16. He Continue Reading
Health

Gov Akeredolu, Deputy Receive COVID-19 Vaccine

Governor Oluwarotimi Akeredolu and his deputy, Mr. Lucky Ayedatiwa have received jab of the oxford-Astrazeneca Covid-19 vaccine in Akure, Ondo State capital. Others, who received the vaccine, are the Deji Of Akure, Oba Aladelusi Aladetoyinbo and the Osemawe of Ondo, Oba victor Kiladejo as well as some top government functionaries.  Speaking after receiving the Continue Reading
Yoruba

Ìjọba Àpapọ̀ Pe Ìpàdé Lórí Pínpín Abẹ́rẹ́ Àjẹsára Covid-19

Alákoso fétò ìlera nílẹ̀ yíì, Dokítà Osagie Ehanire, yóò se ìpàdé pọ̀ pẹ̀lú àwọn alákoso fétò ìlera láti ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì tówà ni orílẹ̀èdè yíì lóni, gẹ́gẹ́ bí ara akitiyan láti ridájúpé, ìsedédé pínpín wáà nídi abẹ́rẹ́ àjẹsára àrùn covid-19. Ẹwẹ ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó sọpé, òhun si ńdúró déè, ìpín tóun, pẹ̀lú àlàyé pé ìgbésẹ̀ ti […]Continue Reading