Home Posts tagged CSRS
Yoruba

Ilésẹ́ ọmọ-ológun sèlérí ọ̀tun lórí ìfẹsẹ̀múlẹ̀ áláfìa

Olórí àwọn ọmọ ológun orílẹ́ẹ̀ ọ̀gágun Gabriel Ọlanisakin, tu fọwọ́ ìgbáradì ilésẹ́ náà sọ̀yà láti sàtìlẹyìn fún ìfẹsẹ̀múlẹ̀ àlafìa jákè jádò àgbáàyé. Ọgagun Ọlonisakin, sọ èyí nílu Abuja, níbi ìfilọ́lẹ̀ ikọ̀ àtìlẹ́yìn àláfìa, PSOS, ibùdó tó ńrísí ìmọ̀ ìwádi CSRS àti ilé-ẹ̀kọ́ tó ńrísí ọ̀rọ̀ Continue Reading