Home Posts tagged Dapọ Abiọdun
Yoruba

Gómìnà ìpínlẹ̀ Ògùn fọwọ́sí gbigba oyè ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ B.Tech nílé ẹ̀kọ́ gbogbonìse Moshood Abiọla

Gẹ́gẹ́ bí ara áyan láti mú àgbéga bá ìmọ̀ ẹ̀rọ àtètò isẹ́ ọwọ́ lórílẹ̀dè yíì ìjọba ìpínlẹ̀ Ògùn ti fọwọ́sí gbígba oyè ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ nípa ìmọ̀ ẹ̀rọ, B.Tech nílé ẹ̀kọ́ gbogbonìse Poly Moshood Abiọla tó wà nílu Abẹokuta, Mapoly. Gómìnà ìpínlẹ̀ náà, ọmọba Dapọ Abiọdun sọ nínú ìwé tó kọ ránsẹ́ sí Continue Reading