Home Posts tagged Dr. Temitope Hussein
Yoruba

Àwọn Dókítà Padà Sẹ́nu Isẹ́ Lẹ́yìn Ìyansẹ́lódì Olósù Méjì

Gbogbo ǹkan ló ti padà bọ̀ sípò báyi nílé ìwòsàn ẹ̀kọ́sẹ́ ìsègùn òyìnbó ìlú ìbàdàn ìyẹn UCH, lẹ́yìn osù diẹ tí ẹgbẹ́ àwọn dókítà tó n fìmọ̀ kún ìmọ̀ láwọn ilé ìwòsàn ìjọba àpapọ̀ ti dasẹ́ sílẹ̀. Gẹ́gẹ́bí akọ̀ròyìn ilé isẹ́ Radio Nigeria sewí, àwọn dókítà tọ́rọkàn ni wọ́n se isẹ́ wọn bóse tọ́ Continue Reading