Home Posts tagged Egungun
Yoruba

Olúbàdàn t’ilẹ̀ ‘bàdàn sèkìlọ̀ fáwọn égúngún láti yàgò fún ìwà jàgídíjàgan lákokò ọdún wọn.

Olúbàdàn tilẹ̀ ìbàdàn ọba Lekan Balogun ti sìkìlọ̀ fáwọn atọ́kùn ègùngùn, àtàwọn tó fẹ́ báwọn kọwọ ọdún pé kí wọ́n yàgò fún jàgídíjàgan lásìkò ayẹyẹ ọdún ilẹ̀ ìbàdàn tí yóò bẹ̀rẹ̀ lósù tó n bọ̀. Ọba Balogun sàlàyé ọ̀rọ̀ yí lásìkò àbẹ̀wò alágbáà tíì se olórí àwọn egùngùn nílé olúbàdàn tó wà ní Continue Reading