Awon olugbe ilu oyo, paapa julo awon alajapa niwon ti sapejuwe bowo epo se tun sadede gbenu soke bayii gegebi egbinrin ote, to je pe base npa kan lomin tun n ru. Akoba to ohun, ti beresi ni se feto oro aje ati irin ajo bayii lawon onisowo npejo so kaakiri ninu oko ati lawon oja. […]Continue Reading
Awon awako ero atawon aladani nilu Ibadan ti koro oju si alekun to de ba owo ori epo lati aadojo naira o din naira meji si ogojo naira, fun jala epo kan. Akoroyin ile ise Radio Nigeria to topinpin boro naa seri laarin igbooro ilu Ibadan jabo pe, opo awon ile epo lo n ta […]Continue Reading