Home Posts tagged Epo Pẹntirol
Yoruba

Àgbáríjọpọ̀ Ẹgbẹ́ Òsìsẹ́ Fún Ìjọba Àpapọ̀ Ní Gbèdéke Ọ̀sẹ̀ Méjì Láti Yọ Àfikún Iye Owó Epo Pẹntirol Àti Epo Pẹntirol

Àgbáríjọpọ̀ ẹgbẹ́ òsìsẹ́ ti setán láti bẹ̀rẹ̀ ìyansẹ́lódì jákèjádò orílẹ̀èdè yi láti ọjọ́ kejì dín lọ́gbọ̀n osù kẹsan, pẹ̀lú bí ìjọba àpapọ̀ se sí dúró lórí àfikún tó filé epo pẹntirol àti iná ọba. Ìgbìmọ̀ alásẹ ẹgbẹ́ òsìsẹ́ nílẹ̀ yí NLC, ti fi ọwọ́sí ìpinu èyí tí ìgbìmọ́ tón sisẹ́ lórí rẹ̀ , Continue Reading