Home Posts tagged Gabriel Ọlanrewaju
Yoruba

Gómìnà Makinde Ní Isẹ́ Àkànse Ìpèsè Iná Ọba Aládani Tìjọba Rẹ̀ Gùnlé Yóò Sànfàní Fáràlú

Gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ onímọ̀ ẹ̀rọ Seyi Makinde ti ní kanse isẹ́ iná ọba aládani tíìjọba òun gùnlé yio wa láti pèsè iná ọba fún ile ìjọba, àwọn ilé ìwé ilé ìwòsàn, àwọn iná ojúpópó àti pápá ìseré láiyọ àwọn ibi tó se kókó min sélẹ̀. Ó sọ̀rọ̀ yí níbi àkànse ìsìn ìdúpẹ́ tó wáyé ní […]Continue Reading