Home Posts tagged Gbenga Ọmọtọshọ
Yoruba

Ìjọba Àpapọ̀ Pe Ìpàdé Lórí Pínpín Abẹ́rẹ́ Àjẹsára Covid-19

Alákoso fétò ìlera nílẹ̀ yíì, Dokítà Osagie Ehanire, yóò se ìpàdé pọ̀ pẹ̀lú àwọn alákoso fétò ìlera láti ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì tówà ni orílẹ̀èdè yíì lóni, gẹ́gẹ́ bí ara akitiyan láti ridájúpé, ìsedédé pínpín wáà nídi abẹ́rẹ́ àjẹsára àrùn covid-19. Ẹwẹ ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó sọpé, òhun si ńdúró Continue Reading