Home Posts tagged Idaabobo
Yoruba

Àwọn ọmọdé pe ìjọba níjà lórí aàbò ọjọ́ ọ̀la wọn.

Àwọn ọmọdé nílu ìbàdàn tíi solúùlu ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ti késíjọba láti sàgbékalẹ̀ àwọn ìlànà kan tí yóò dábobo ọjọ́ ọ̀la wọn. Lákokò tíwọ́n ńbá ilé-isẹ́ Radio Nigeria sọ̀rọ̀ ni wọ́n pè féyíì, pẹ̀lú àlàyé pé, àwọn ọjọ́ ọ̀la ilẹ̀ Nìajírìa, torina ló fi sepàtàkì fún ìjọba àtàwọn tọ́rọkàn, láti jẹ́ Continue Reading