Home Posts tagged Idagbasoke
Yoruba

Ìjọba Apapọ̀ Ti Gbé Orùkọ́ Ipínlẹ̀ Mọ́kànlélógún Jáde Ti Wọ́n Yo Ni Ibùdó Iselọ́jọ̀ Fún Kíkó Eran Jẹ̀

Pẹ̀lú bí ìgbésẹ̀ láti mú àyípadà dé bá ńkan ọ̀sìn nílẹ̀ yí, ìjọba àpapọ̀ ti ní kí ibùdó tí wọ́n yo ti ma kẹ́ran jẹ̀, tí wọ́n yà sọ́tọ̀, kó gbérasọ, nípinlẹ̀ mọ́kàndínlógún láriwá ilẹ̀ yí, tófimọ́ ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ àti Ògùn lẹ́kùn ìwọ̀ orun gúsù ilẹ̀ yí. Nígbà tón sọ̀rọ̀ nílu Abuja, lásìkò ìpàdé Continue Reading
Yoruba

Àrẹ Muhammadu Buhari Tẹpẹlẹmọ́ Wíwójùtú Sí Ipèníjà lórí Etò Abò

Àrẹ Muhammade Buhari ti sọ pé àmúgbòrò yo de bá ìgbáyé gbádùn àwọn èyàn nílẹ̀ Nàijírìa, bẹ̀rẹ̀ nípa ìpèsè ètò àbò tó múnádóko. Nílu Maiduguri, l’afin Shehu ti Borno, ni àrẹ ti sọ̀rọ̀ ìdánilójú yi . Àrẹ ẹni tó ń se àbẹ̀wò ẹnu isẹ́ ọlọ́jọ́ kan sípinlẹ̀ Borno, ló ti kọ́kọ́ se ìpàdé pọ̀ pẹ̀lú […]Continue Reading