Ajo Isokan Ile Europe ti sofun ijoba apapo wipe gbigbogunti igbesunmomi, laapaa ariwa ila oorun ati awon ipenija leka abo jakedado ile yii, koja fifi awon omo ogun sowo sawon agbegbe ti ipenija waye. Nigba to nba awon oniroyin soro, saaju ayeye ojo Europe fun todun yii, olori iko ile europu Continue Reading
Ajo isokan agbaye ti bere fun igbese iko owo to to billion kan dollar ti se owo ile okere jo lati fi se iranlowo fun awon aeniyan to le ni million mefa ni ekun ariwa ila orun, to fi mo awon eniyan ti isele kan tabi omiran ti si ni ipo pada lati ara rogbodiyan […]Continue Reading