Home Posts tagged Ikilo
Yoruba

Àjọ NAFDAC, se ìfilọ́lẹ̀ ìpolongo tako ìpèsè óunjẹ inu agolo tí kò péye.

Àjọ tó ń rísí ipeniye ohun tẹ́nu ń jẹ àti mimu pẹ̀lú egboogi lórílẹ̀èdè yí, NAFDAC, ti se ìfilọ́lẹ̀ tí kò pe níye, ǹkan ìpara tó léwu, omi inu ọrọ ti kò peye àti àwọn ǹkan ilo gbogbo tó kù diẹ káàto. Olùdarí àgbà  àjọ NAFDAC, ọ̀jọ̀gbọ́n Mojisọla Adeyẹye ló se ìkìlọ̀ yí lásìkò tó […]Continue Reading
Yoruba

Ati wọlé sílé ẹ̀kọ́ ìmọ̀ nọ́ọ̀si: Iléesẹ́ olóògun òfurufú sèkìlọ̀ fáràlú nítorí àwọn oníjìbìtì

Iléèsẹ́ olóogun ofurufu ilẹ̀ yí ti sèkìlọ̀ fáwọn ọmọ orílẹ̀èdè yí tó n lépa àti wọlé sílé ẹ̀kọ́ gíga ìmọ̀ nọ́ọ̀si pé kí wọ́n sọ́ra kí wọn ma báà bọ́ sọ́wọ́ àwọn oníjìbìtì. Ìkìlọ̀ yí ló wáyé nípa ayédèrú ìwé ìgbaniwọlé sílé ẹ̀kọ́ náà tó ń lọ káàkiri orí ẹ̀rọ ayélujára. Olùdarí ètò ìròyìn ọ̀hún […]Continue Reading