Àjọ tó ń rísí ipeniye ohun tẹ́nu ń jẹ àti mimu pẹ̀lú egboogi lórílẹ̀èdè yí, NAFDAC, ti se ìfilọ́lẹ̀ tí kò pe níye, ǹkan ìpara tó léwu, omi inu ọrọ ti kò peye àti àwọn ǹkan ilo gbogbo tó kù diẹ káàto.

Olùdarí àgbà  àjọ NAFDAC, ọ̀jọ̀gbọ́n Mojisọla Adeyẹye ló se ìkìlọ̀ yí lásìkò tó ń síde ètò náà nílu Abuja.

Olùdarí àgbà náà sàlàyé wípé, èrèdí ètò ìpolongo náà ní láti se àtẹnumọ́ àti àmúgbòrò ojúse àjọ náà lọ́nà tí àwọn aráàlu kò fi ní bọ sínú ewu ayádèrú ńnkan tí wọ́n nílò.

Ọjọgbọn Adeyẹye sàlàyé wí pé àkọmọna ètò ipolongo náà ni ifẹsẹmulẹ ètò ìlera tó péye faraalu wípé yíyàgò fún àwọn tó ń ta egbogi alakapọ, àwọn tó léwu fún ago ara ẹ̀dá nínú ìpèsè oun tẹ́nu ńjẹ.

Babatunde Salaudeen.  

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *