Home Posts tagged Ile Amerika
Yoruba

Ìjọba àpapọ̀ lu ilẹ̀ Amẹrica lọ́gọ ẹnu lórí ìrànwọ́ fún ìgbógun ti ìgbésùmọ̀mí

Àarẹ Muhamadu Buhari ti fẹ̀mí ìmoore hàn sí àwọn alásẹ ilẹ̀ Amẹrica lórí bí wọ́n se gba ilẹ̀ Nàijírìa láàye láti ra ohun ìjagun fún gbígbógun ti ìgbésùmọ̀mí tó fimọ́ ètò ìdánilẹ̀kọ tíwọ́n se fáwọn ọmọ ogun ilẹ̀ Nàijírìa. Àarẹ Buhari sọ̀rọ̀ náà nílu Abuja lásìkò tón gbàléjò akọ̀wé ìjọba ilẹ̀ Continue Reading