Home Posts tagged Ilé Ẹ̀kọ́
News Yoruba

Àjọ JAMB Fòfinde Gbigba Akẹ́kọ́ọ̀ Wọlé Sáwọn Ilé Ẹ̀kọ́ Gíga Lailọ́wọ́ Àjọ Náà

Àjọ tón rísí ètò ìdánwò gíga ti fòfinde gbígba akẹ́kọ́ọ̀ yowu wọlé sáwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga tón bẹ nílẹ̀ yíì lai lọ́wọ́ òhun nínú, laifi ti ìpele ẹ̀kọ́ yóòwù se. Olórí ẹ̀ka tón rí sọ́rọ̀ ìròyìn àtàgbékalẹ̀ ìlànà lájọ Jamb, ọ̀mọ̀wé Fabian Benjamin ló kéde yíì nínú ìwé ìròyìn ọlọ́sọ́ọ̀sẹ̀ wọn tíwọ́n Continue Reading