Home Posts tagged Ile Igbimo Asofin Agba
Yoruba

Ilé ìgbìmọ̀ asòfin àgbà setán láti sàtúngbéyẹ̀wò òfin ilé gbe ìjọba àpapọ̀

Adarí ilé ìgbìmọ̀ asòfin àgbà ilẹ̀ yíì, ọ̀mọ̀wé Ahmed Lawan sọpé ilé ti setán láti sàtúngbéyẹ̀wò òfin tó síse pẹ̀lú ilégbe ìjọba àpapọ̀ láti mú ìdúró réè bá ẹ̀ka náà kíì ìfẹsẹ̀múlẹ̀ tílẹ̀lé ìlànà yíì fáwọn ilésẹ́ aládani jẹ́ títẹ̀lé sansan. Ọmọwe Lawan sọ èyí lásìkò tíì olùdarí ilésẹ́ tó ńrísí ilégbe ìjọba àpapọ̀, ọ̀gbẹ́ni […]Continue Reading