Home Posts tagged Ilé isẹ́ àrẹ
Yoruba

Ilé isẹ́ àrẹ sèkìlọ̀ lórí ọ̀rọ̀ tólèdomi ìsọ̀kan ilẹ̀ yíì rú

Ilésẹ́ àrẹ ti sàpèjúwe ìpè àtúntò ilẹ̀ yíì látọ̀dọ̀ àwọn kan gẹ́gẹ́ bí ohun tí kóò lẹ́tọ nírúfẹ́ àkókò yíì. Olùránlọ́wọ́ pàtàkì sárẹ fọ́rọ̀ ìròyìn àti ìbáráàlu sọ́ọ̀rọ̀, Mallam Garba Shehu sọ èyí nínú àtẹ̀jáde kan tófisíta nílu Abuja. Mallam Shahu sọpé irúfẹ́ ìpè Continue Reading