Yoruba

Ilé isẹ́ àrẹ sèkìlọ̀ lórí ọ̀rọ̀ tólèdomi ìsọ̀kan ilẹ̀ yíì rú

Ilésẹ́ àrẹ ti sàpèjúwe ìpè àtúntò ilẹ̀ yíì látọ̀dọ̀ àwọn kan gẹ́gẹ́ bí ohun tí kóò lẹ́tọ nírúfẹ́ àkókò yíì.

Olùránlọ́wọ́ pàtàkì sárẹ fọ́rọ̀ ìròyìn àti ìbáráàlu sọ́ọ̀rọ̀, Mallam Garba Shehu sọ èyí nínú àtẹ̀jáde kan tófisíta nílu Abuja.

Mallam Shahu sọpé irúfẹ́ ìpè bẹ́ẹ̀ máà dún mowuru mo ibasawo tó yèkoro orílẹ̀èdè yíì.

Ó tọ́kasi pé ètò ìsèjọba tówà lóde báyíì, kòní gbé ìgbésẹ̀ yóòwu tóbá tako ìfẹ́ arálu tàbí tóbá léè dá ìbẹ̀rù-bojo sílẹ̀.

Net/idogbe

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *