Home Posts tagged Ilé-isẹ́ ọlọ́pa
News Yoruba

Ilé-isẹ́ ọlọ́pa ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ti fọkàn àwọn èèyàn Sókà balẹ̀ lórí àhesọ ọ̀rọ̀ kan tó wáyé.

Ilé- ẹ̀kọ́ gíga fasity Leadcity ìbàdàn ti sàlàyé pé, àwọn ọ̀dọ́ tó wá látapá àríwá ilẹ̀ yíì, pẹ̀lú ọkọ̀ akérò bus ńlá kan wá ságbègbè sókà lọ́jọ́ ajé, akẹ́kọ́ọ̀ ilé-ìwé náà niwọ́n se. Sáajú níbẹ̀rẹ̀ ọ̀sẹ̀ yíì nìròyìn náà gbòde kan pé, bí ọ̀ọ̀dúnrún àwọn tíwọ́n furasí bí darandaran ti yawọ Continue Reading