Home Posts tagged Iléèsẹ́ Agbóhùnsáfẹ́fẹ́
News Yoruba

Àjọ NBC, Sèlérí Àmójútó Tó Péye Fáwọn Iléèsẹ́ Agbóhùnsáfẹ́fẹ́

Ó se pàtàkì fáwọn agbóhùnsáfẹ́fẹ́ láti ní ìmọ̀ kíkún wípé isẹ́ tí wọ́n yàn láàyo. Torí bíì èyí, ó pọndandan fún wọn láti máà tẹ̀lé ìlànà àti òfin tó de isẹ́ náà. Èyí ni èrò olùdarí àjọ tó ń se kòkárí àwọn iléèsẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ lórílẹ̀èdè yí, ẹkùn gúùsù ìwọ̀orùn, ọ̀gbẹ́ni Raphael Akpan lásìkò Continue Reading