Ileese olopa ile yi ti tepele mo igbiyanju lori ipese aabo to peye fawon ileese ati olori jori ton se amulo opopona marose Ibadan silu Eko. Igbakeji oga agba ileese, Olopa ile yi fun ekun keji, Ogbeni Johnson Kokumo lo fowo oro yi soya nilu Abeokuta lasiko abewo lenu ise to se si Gomina Continue Reading
Lasiko ijoko ile, lati mu ki agbega de ba ilese ohun, ati aba ofin lori idasile ileeko ti won yo ti maa ko nipa ile olopa, Ogbeni Yusuf Gagdi tenumo ipinnu ile ise olopa atawon eka to se koko. Gegebi asofin naa tiwi, gbigbe liana kale ti yio risi asiko ti IGP yoo lo ninu ofiisi […]Continue Reading
Saaju eto idibo Gomina ti yoo waye lola nipinle Edo, oga agba yanyan funleese Olopa ile yi, Ogbeni Mohammed Adamu ti pase pe ki opin ba igbokegbode oko nipinle naa lati oru oni titi di aago mefa irole ola. Ninu atejade ti agbenuso ileese Olopa ile yi DCP Frank Mba fi sita ni Oga Agba […]Continue Reading