Yoruba

Ile Igbimo Asofin gba Lero pe ki Ogaagba Olopa Ma lo Saa Odun Merin

Lasiko ijoko ile, lati mu ki agbega de ba ilese ohun, ati aba ofin lori idasile ileeko ti won yo ti maa ko nipa ile olopa, Ogbeni Yusuf Gagdi tenumo ipinnu ile ise olopa atawon eka to se koko.

Gegebi asofin naa tiwi, gbigbe liana kale ti yio risi asiko ti IGP yoo lo ninu ofiisi ni saa kan ni yio mu mu ki ileese olopa tunbo sise daganjia si, nibamu pelu liana igbanisise, idanileko loorekoore to fimo titi owo naa gba fun awon ise to se koko.

Afonja

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *