Home Posts tagged James Faleke
Yoruba

Ilé ìgbìmọ̀ asòfin jẹ́jẹ láti fọwọ́ òfin mú àwọn ilésẹ́ tokọ̀ láti sanwó tó yẹ sí koto jọba

Ilé ìgbìmọ̀ asòfin tiń ńdú koko pé, òn yo sàmúlò ọwọ́ òfin, fi de àwọn ilésẹ́ kan tí wọ́n kọ̀ láti san àwọn owó tó yẹ sí koto ìjọba àpapọ̀. Alága ìgbìmọ̀ ìsúná nílé asòfin James Faleke ló sọ̀rọ̀ yí lásìkò ìfọ̀rọ̀wérọ̀ pẹ̀lú àwọn ilésẹ́ ìjọba nílu Abuja. Ó tọ́kasi pé, àjọ tón mójútó ìpéye […]Continue Reading