Yoruba

Ilé ìgbìmọ̀ asòfin jẹ́jẹ láti fọwọ́ òfin mú àwọn ilésẹ́ tokọ̀ láti sanwó tó yẹ sí koto jọba

Ilé ìgbìmọ̀ asòfin tiń ńdú koko pé, òn yo sàmúlò ọwọ́ òfin, fi de àwọn ilésẹ́ kan tí wọ́n kọ̀ láti san àwọn owó tó yẹ sí koto ìjọba àpapọ̀.

Alága ìgbìmọ̀ ìsúná nílé asòfin James Faleke ló sọ̀rọ̀ yí lásìkò ìfọ̀rọ̀wérọ̀ pẹ̀lú àwọn ilésẹ́ ìjọba nílu Abuja.

Ó tọ́kasi pé, àjọ tón mójútó ìpéye óujẹ àti ògùn àti ilésẹ́ epo rọ̀ọ̀bì gẹ́gẹ́bí ara àwọn tíkò san on tótọ́ fún ìjọba.

Ọgbẹni Faleke sọ pé ilésẹ́ yi lón mú kí owó tón wọlé lábẹ́lé kéré jọjọ, tó sì sọpé kò bófinmu kí àwọn ilésẹ́ yi kan ma náà owó tí kò sí nínú ètò ìsúná, tẹ́lẹ̀

Ololade Afọnja

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *