Home Posts tagged káàdi ìdánimọ̀
Yoruba

Alákoso ọ̀rọ̀ abẹ́lé kọminú lórí owó ribiribi fún ìpèsè káàdi ìdánimọ̀ ilẹ̀ yí

Aákoso fọ́rọ̀ abẹ́lé nílẹ̀ yí, ọ̀gbẹ́ni Rauf Arẹgbẹsọla ti sọ̀rọ̀ di mímọ̀ pé, káàdi ìdánimọ̀ ill yí tuntun fáwọn ọmọ ilẹ̀ yí yóò na ìjọba ní òbítíbitì owó. Ọgbẹni Arẹgbẹsọla sípaya ọ̀rọ̀ yí fáwọn oníròyìn nílu ilésà pẹ̀lú wí pé number fún káàdi ìdánimọ̀ ilẹ̀yí tó se pàtàkì lákokò yí fún gbogbo Continue Reading