Home Posts tagged kolounkigbe
Yoruba

Ibẹ̀rù bojo koloun kigbe mú kí ètò ọ̀rọ̀ ajé pakasọ nílu ọ̀yọ́

Ibẹ̀rù bojo ìkọlù látọ̀dọ̀ àwọn molọ kólóun kígbe tón sàkóbá fún kárà kátà nílu ọ̀yọ́ láti àná, ló sin tẹ̀síwájú lóòrọ òní. Akọ̀ròyìn ilésẹ́ Radio Nigeria tón tópinpin ìsẹ̀lẹ̀ yi jábọ̀ pé, àwọn ilé ìfowópamọ́ lágbègbè náà ní àwọn kò ti sí ilẹ̀kùn rẹ̀, láti má da àwọn oníbarà loun lẹ́yìn tí wọ́n Continue Reading