Home Posts tagged lórílẹ̀èdè Ghana
Yoruba

Ìjọba àpapọ̀ sèlérí fáwọn òntàjà ọmọ ilẹ̀ yíì tówà lórílẹ̀èdè Ghana

Igbákejì àarẹ orílẹ̀èdè Nàijírìa Yẹmi Ọsinbajo ti fidá àwọn ọmọ ilẹ̀ yíì tó ńtajà lórílẹ̀èdè Ghana lójú wípé ìdájọ́ òdodo yówayé lórí ohun tí wọ́n jìjàdù rẹ̀ pẹ̀lú ìjọba ilẹ̀ Ghana. Ọjọgbọn Ọsinbajo, ẹnitó sèpàdé pọ̀ pẹ̀lú àwọn asojú ọmọ ilẹ̀ yíì tíwà ni Accra, Ghana fọwọ́ ìdánilójú ìpinu ìjọba Continue Reading