Wọ́n ti gbàwọn tóngbóhùn sáfẹ́fẹ́ látorí ẹ̀rọ ayélujára àtàwọn olùdásílẹ̀ rẹ̀ níyànjú láti jẹ́ akọ́sẹ́mọsẹ́ nídi isẹ́ tíwọ́n yàn láayo. Alájutó àgbà ilé-isẹ́ ẹlẹ́rọ amìnlújìnjìn Premier tó wà nílu ìbàdàn, Ẹniọ̀wọ̀ Niyi Dahunsi ló gbọ̀rọ̀ àmọ̀ràn yíì kalẹ̀, lákokò tó ń gbéwe àpilẹ̀kọ kan kalẹ̀ Continue Reading