Home Posts tagged Mr Festus Oyebade
Yoruba

Gómìnà Oyetọla fọwọ́sí sísan àjẹlẹ àjẹmọ́nú àwọn òsìsẹ́ fẹ̀yìntì

Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọsun, ọ̀gbẹ́ni Adegboyega Oyetọla ti buwọlu yíyọ̀nda owó tóòléní ẹdẹgbẹrin milliọnu naira, láti san owó àjẹmọ́nú àwọn òsìsẹ́ fẹ̀yìntì nípinlẹ̀ náà. Olórí òsìsẹ́, ọ̀gbẹ́ni Festus Oyebade ẹnitó sọ èyí nílu Òsogbo, sọpé, owótólédiẹ lẹdẹgbẹta milliọnu naira lára owó ohun lójẹ́ Continue Reading