Home Posts tagged Mrs Achinam Fidel
Yoruba

Ìjọba àpapọ̀ gùnlé ìgbésẹ̀ láti mátunse bá àwọn tó ti farakásá ìsẹ̀lẹ̀ ìfipábánilòpọ̀

Ìjọba àpapọ̀ ti kéde mímú àtúnse tó gbọgbọ́n bá àwọn tó ti fara káaká ìwà ìfipábánilòpọ̀ lórílẹ̀èdè yíì. Alákoso kejì fọ́rọ̀ ilésẹ̀ okòòwò àti ìdókoowò Arábìnrin Mariam Katagum kéde èyí nílu Abuja. Ó sọpé, ilésẹ̀ náà nípasẹ̀ àwọn àjọ tówà lábẹ́ rẹ̀ yóò sàtìlkyìn tóní tumọ̀ fáwọn tó ti fara-kásá Continue Reading