Ìjọba àpapọ̀ ti kéde mímú àtúnse tó gbọgbọ́n bá àwọn tó ti fara káaká ìwà ìfipábánilòpọ̀ lórílẹ̀èdè yíì.

Alákoso kejì fọ́rọ̀ ilésẹ̀ okòòwò àti ìdókoowò Arábìnrin Mariam Katagum kéde èyí nílu Abuja.

Ó sọpé, ilésẹ̀ náà nípasẹ̀ àwọn àjọ tówà lábẹ́ rẹ̀ yóò sàtìlkyìn tóní tumọ̀ fáwọn tó ti fara-kásá ìwà ìfipábánilòpọ̀ ọ̀hún, nípa kíkọ́wọn nísẹ́ ọwọ́, rírówọn lágbára àti dídáwọn lóokoowòo.

Nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀ igbákejì ọ̀gá tó wà fọ́rọ̀ àbùdá lákọ-lábo nílésẹ́ náà, arábìnrin Achinam Fidel sọpé pàtàkì ẹ̀ka náà níì láti se kóríyá fáwọn obìnrin nídi kíkópa nínú ìdáskajésílẹ̀, okòowò tó ti mọ ẹ̀ka ìjọba gbogbo.

Net/Elizabeth Idogbe

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *